SCROLLS

SCROLLS

ANU NI MO FE

    Anu Ni Mofe Lyrics

        ....by Aduke Gold


Anu Ni Mo Fe is a single off the self titled album “Anu Ni Mofe” released in 2018 under Balm of Gilead records.
Other songs are
:
-Eniyan no gbogbo
-Gracious and Overtaking
-So yeye Mi Di Ayeye

   
ANU NI MOFE_ADUKE GOLD
Verse 1

Iwo nikan Lomoju, to Peju, to funfun ju
Iwo nikan Lorinu, to rankan Gbogbo eniyan
Iwo nikan La o le sigba fun, ta o le binusi, tao le da lebi
Bo Tinwu o Lo n sola, lo n pin fun gbogbo eniyan

O se faraohu laya le,o si ran moose ko lo ba
Orilede meji nbe Ninu re,aburo laa ma soga egbon
Jephta omoale, o tun mu pada wa je oluomo
Kato de itere Lojo idajo, Ojo anu ni ko....

Chorus

Aanu ni mofe
anu ni mobere
anu ni mofe o
Baba, ise ko lowo....download other songs by Aduke Gold 
@ www.scrolls.com.ng

Post a Comment

0 Comments